DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko...

17
DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO TAN IMQLV KARIAYE A n pe yin si DIDE, TAN IMQLV ti qdun 2015, qjq keji ozu kqkanla Qjq Adura Vgbv Obinrin Onitvbqmi Lagbaaye. Vka Obinrin Ijq Onitvbqmi Lagbaaye jv akojqpq vgbv lati vkun meje ti wqn n zoju orilv ede mejidinlogoji-le-ni igba vgbv Obinrin lati orilv ede mejidin-logoje. Igbimq Vka eto Vgbv Obinrin Lagbaaye ni o ze agbekalv eto qdun 2015. BWA Women’s Department 405N. Washington Street Falls Church, VA 22046. USA Tel: +1(703)790-8980 Fax +1(703)663-8269 Email: [email protected] Web: www.bwawd.org

Transcript of DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko...

Page 1: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO TAN IMQLV KARIAYE

A n pe yin si DIDE, TAN IMQLV ti qdun 2015, qjq keji ozu kqkanla Qjq Adura Vgbv Obinrin Onitvbqmi Lagbaaye. Vka Obinrin Ijq Onitvbqmi Lagbaaye jv akojqpq vgbv lati vkun meje ti wqn n zoju orilv ede mejidinlogoji-le-ni igba vgbv Obinrin lati orilv ede mejidin-logoje. Igbimq Vka eto Vgbv Obinrin Lagbaaye ni o ze agbekalv eto qdun 2015. BWA Women’s Department 405N. Washington Street Falls Church, VA 22046. USA Tel: +1(703)790-8980 Fax +1(703)663-8269 Email: [email protected] Web: www.bwawd.org

Page 2: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

DIDE, TAN IMQLV Nigba ti a ba dide soke Oun yoo tan kariaye. “Dide, tan imqlv: nitori imqlv rv de, ogo Oluwa si yqq lara rv (Isaiah 60:1). Eto Qjq Adura Lagbaaye ti Vgbv Obinrin Onitvbqmi ti Qdun 2015 tun bvrv akori qrq titun fun qdun marun-un miiran “DIDE, TAN IMQLV” fun qdun marun-un ni a o fi kq vkq yii nigba ti a ba dide soke Oun yoo tan kiri agbegbe, yoo tan ninu izqkan izododo ati izv isin wa gbogbo. A gbero lati pari erongba wa ti idagbasoke mvjq ti akoko yii ti a pe ni ‘Eight Millennium Development Goals’ Ibo ni v baa de? Iroyin 2010 awqn obinrin ni yoo ran wa lqwq lati mq kin ni azeyqri eto (MDGS). Eto MDGS ti o jv mq eto ilera ze pataki fun atunze eto igbe aye awqn eniyan. Qdun mvwaa ti o kqja lq mu iku awqn qmqde dinku ni gbogbo agbaye. Sibvsibv ilv alawq dudu (Africa) ni iku awqn qmqde pq si pvlu itiraka lati din-in ku. Erongba MDGS tun ni lati mu ki ilera awqn iya duro deede. O ze pataki ki o wa ni arqwqto wqn ni akoko iloyun ati ibimq, lati qdq awqn eleto ilera ti o kun oju osunwqn ni eleyii ti le zeeze. Iwadii fihan pe qpq awqn obinrin ni o n gba itqju ninu oyun zugbqn sibv aaye wa fun itvsiwaju. Itvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani dun wqn, ida meji ninu ida mvta ninu igba mvrin din mvfa miliqnu agbalagba ti ko mqqn kq mqqnka eyi ti a ko ri iyipada lati qgun qdun svyin. Lati qdun 1990-2010 ni ikopa awqn obinrin ninu izv zize lagbaye ko yatq si bi o ze wa. Zugbqn bi ilaji awqn ti o n kopa ti ko si ju ida qgbqn lq ni Africa ati Asia. Kaakiri agbaye ni a ti ri pe bi ida mvtadinlogun pere ni ipo ti awqn obinrin di mu ninu eto izakoso ti ijqba. Akqsilv mu daju pe ni ibi gbogbo ni awqn obinrin ti ni idojukq bi o tilv yatq lati ibikan si ibomiran. Jagidi-jagan yii wa lori eto qrq aje, ibanilopq lqna aitq ati bvvbvv lq ti awqn ti o si wa ni idi qrq naa jv awqn ti o sun mq wqn. Ipo ilegbe (ile gbigbe) ati awqn ajalu lorizirizi a maa ze akoba pupq fun awqn obinrin ni awqn orilv ede ti o zvzv n dagba, paapaa nipa awqn izv ti ko lere ati ilera. Ni qpqlqpq ilegbe ni igberiko ati ilu nla ni wqn ko ni anfani si omi vrq ti o mq gaara fun mimu. Ni awqn apa ibikan ni agbaye ni o jv pe awqn iya ati awqn qmqbinrin wqn ni wahala airijv airimu maa n mu lomi ju awqn qkunrin lq. Izv a maa zv awqn obinrin ju qkunrin lq ninu ile. Ibeere wa akqkq naa ni pe ibo ni a de duro? Nibo ati bawo ni a ze le tan fun Oluwa. Awqn ibeere ti a o maa dahun fun qdun marun niyi ninu eto Qjq Adura Vgbv Obinrin Onitvbqmi Lagbaaye bi A Ze n DIDE TAN IMQLV. Vsv Bibeli wa ni ibvrv n sq fun wa pe ki a dide ki a si jv ki imqlv wa tii ze Jesu Kristi tan fun araye ri. Adura wa ni pe eyi yoo jv ifv qkan yin lati tan imqlv fun Oluwa.

Page 3: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

V lq si vrq ayelujara BWA Women’s Department Website wwwbwawd.org- click on 2015DOP, fun vkunrvrv alaye. Patsy Davis Oludari Agba BWA Women’s Department.

Page 4: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

DIDE, TAN IMQLV

Awqn Obinrin Onitvbqmi Lagbaaye tun n parapq lvvkan sii lati ze igbelarugv qjq Adura Vgbv Obinrin. Qjq yii jv qjq pataki siwa lati ko ara wa papq ki a si ze ififunni, a si tun maa fun wa ni aafani lati gbq itan ni qkankojqkan awqn obinrin kaakiri agbaye ti wqn dide lati sin Qlqrun. Ibi yoowu ti wqn le wa imqlv Qlqrun n tan lori izv isin wqn. Nipazv qjq Adura Obinrin Onitvbqmi Lagbaaye a n dara pq lati tan tori adura wa ati qrv wa ni o n gbe wqn ro. Qlqrun n pe wa lati dide ki a si tan imqlv ninu izv isin Rv. Lati akoko yii lq fun qdun marun-un ni a o ma lo akqle yii iru ipo ti o le wu ki a wa ninu vmi tabi ninu ara, o zeeze fun wa lati dide ki a si sa ipa wa ninu izv Qlqrun. Jesu sq fun wa pe Oun ni imqlv aye. Imqlv yii ni o yv ki o tan lara wa nigba ti a ba n sin-In bi a ze n sin awqn eniyan miiran. Imqlv ti I ze Kristi ti o n gbe ninu wa gba wa ni aaye lati tan tori pe Jesu tun fikun pe “Vyin ni imqlv aye. Bi a ze n ni ipade yii ni a n pe ara wa nija lati jade lq tan imqlv nibi yoowu ti a le lq. A gbadura pe ibukun ni ipade yii yoo jv fun yin, ki v si ni ifarakinra ti vmi pvlu awqn arabinrin wa ni agbaaye bakan naa, a n pe wa nija lati dide tan imqlv Qlqrun yoo bukun yin.

Raquel Contreras

Alaga (2010-2015) BWA Women’s Department.

Page 5: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

V Ze Ipalvmq Fun Qjq Adura Yin

Ipalvmq: O ze pataki ki awqn igbimq ti o wa fun ipalvmq tete bvrv izv, ti eto naa yoo fi fun awqn Obinrin Onitvbomi ni aaye kikun lati ni ipa fun Kristi bi wqn ze n dide tan imqlv. Awqn igbimq fun ipalvmq nilo lati pinnu qna ti o dara julq ti awqn obinrin onitvbqmi yoo fi gbadura – eto wqn qjq aje tii ze qjq keji ozu kokanla ni a ya sqtq, ti eto yii ko ba zeeze ni qjq ti a ya sqtq, v le ze e ni opin qsv tabi igba miiran gvgv bi eto adura iyara vni si apakan tabi ni qjq qsv (Sunday) ki gbogbo ijq le kopa nibv. Ohun ti o ze pataki ni lati gbe eto ti o le ze awqn obinrin yin ni anfani kalv ninu ozu kqkanla. V fi ipe pataaki sita pvlu awq ti o duro fun ami BWA Women’s Department Website at www.bwawd.org labv qjq Adura 2015. Ede oyinbo ni zugbqn v le tumq rv si ede abiibi yin. V polongo eto yii pvlu ori qrq DIDE TAN IMQLV, tabi ki v lo qgbqn atinuda tiyin lati fi orizirizi qna bii sinimq, awqn obinrin lorizirizi pe awqn eniyan si eto Qjq Adura Obinrin Onitvbqmi. V le ze eleyi ni akoko isin ninu ijq yin ati awqn ipade miiran. V le lq si ori afvfv vrq ayelujara (facebook) fun ipolongo pvlu ibi gbogbo ti awqn obinrin ti le maa pejq. V pese apowe fun qrv gbigba silv pvlu aworan awqn vkun kqqkan, v ran awqn eniyan leti lati jv olotitq ninu ififunni wqn ki a le ko ipa ti o jqju ni gbogbo agbaye fun Kristi. Awq elese aluko ni ti Afrika (purple), awq sanmq buluu rvsurvsu (blue) ni ti Asia, awq ewe (green) ni ti Caribbean, buluu ti o dudu (dark blue) ni ti Europe. Awq yvlo ni ti Latin America. Awq omi qsan (orange) ni ti North America, Awq pupa yoo (red) ni ti South West pacific. Ni ara apowe v lo aworan DIDE TAN IMQLV ki v fi aaye orukq ati iye ti o wa ninu apowe silv niwaju apowe. Zize Agbekalv

Ikini Alaga Vka Vgbv Obinrin Lagbaaye

V ze agbekalv ikini alaga gvgv bi ifqrq wa ni lvnu wo. Ki qmqbinrin kan duro bi Alaga ki qmqbinrin miiran duro bi vni ti o n fi qrq wani lvnu wo ki v lo awqn qrq ti o wa ninu ikini Alaga la ti ze isqrq n gbesi. V lo akoko naa lati sq nipa ori qrq titun ti o wa niwaju iwe eto. V gbe eto naa kalv daadaa ki o dabi vnipe n ze ni v n ka iroyin ati iroyin awqn obinrin ni agbaye 2010 bi koko qrq miiran ba wa; v le lo iwe iroyin agbegbe yin kan, tabi Komputa bi igba ti o jv inu rv ni v ti n ka a. v si tun le kq q jade bi iroyin ki v si kaa. Vkq Bibeli: V yan vnikan ki o ti pese vkq Bibeli ziwaju akoko yii. V kq Bibeli meji ni o wa. Qkan ni a tv jade v le ri ekeji ni ori vrq ayelujara ti Vka Vgbv Obinrin www.bwawd.org-click. Qjq Adura Lagbaye. Alaye Lori Qrv Qrv ti a ba gba ni qjq yii ni a fi n n ze iranlqwq fun awqn izv iransv Vka Vgbv Obinrin Onitvbqmi Lagbaaye. Orisun kan ti o ze pataki julq niyi fun vka yii lati ri owo. V gba

Page 6: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

awqn obinrin niyanju lati mu qrv ti o jqju ju ti qdun ti o kqja wa. V jv ki o ye wqn pe qrv ti wqn ba mu wa ni a o dapq mq ti gbogbo awqn obinrin yooku ni awqn vkun yooku lati fi ni ipa ni gbogbo agbaye fun Kristi. Bi a ze maa n Pin Qrv Qjq Kan Yii: Ilaji owo qrv yii ni a maa n fi silv ni vkun nigba ti a n fi ilaji yooku ranzv si ile-izv Vgbv Obinrin Onitvbqmi ni Agbaye.

Page 7: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

Vkq Bibeli … Lvzvkvzv, O dide, o si n ze izv isin rv

Dide ki O Tan Imqlv

38. Nigba ti o si dide kuro ninu sinagqgu, o si wq ile Simoni lq, iba si ti da iya aya Simoni wolv; wqn sib v nitori rv.

39. O si duro tiiri si, o ba iba naa wi; iba si jqwq rv lqwq; o si dide lqgan, o n ze iranzv fun wqn. (Luku 4:38,39).

Qkan ninu izesi ati iwa izv iranzv Jesu nigba ti o wa lori eepv ni qna ti o gba fi arakinra pvlu awqn obinrin. O jv oniwa tutu, alaanu, ju gbogbo rv lq a maa bqwq fun awqn eniyan. A ri awqn nnkan wqnyi ninu awqn akqsilv ajqzepq Rv pvlu wqn.

Ninu iriri ti oni o ri iru ihuwasi ti ko wqpq nigba naa, pe bi Jesu ze n lq lati igberiko de igberiko, ilu si ilu ninu eruku ilv Palvstini. Ki I ze ododo ijqba qrun nikan ni Jesu n zalaye fun wqn ninu qrq ifv ati aanu, sibv ninu izesi Rv O n ze afihan ayipada ti o yv ki o ba igbaye gbadun awqn eniyan akoko naa.

Ni qsan gangan qjq abamvta lvyin ti Jesu ti kq awqn eniyan ti o si ti ze izv iyanu iwosan ni Sinagqgu ti Kapanqqmu. Peteru mu Jesu ati awqn qmq vyin lq si ile rv tori ki wqn o le lq sinmi. Lqgan ti wqn de ibv ni wqn sq fun Jesu pe iya-iyawo Peteru ko gbadun. O zeeze pe opo ni iya agba naa ti o si kun fun qpqlqpq aini zugbqn ti awqn eniyan rv si nifv rv pupq ti wqn si jv ki Jesu mq pe ipo ti o wa ko tv awqn lqrun. Ti wqn si mq pe O lagbara lati ze iwosan rv tori pe O ti wo qkunrin kan ti o ni vmi aimq san ni owurq. Ni akoko yii ohun ti o lewu ni ki eniyan ni arun iba, aisan buruku gbaa ni o jv. Eyi fi idi otitq yii mulv nigba ti Luku paapaa ti o jv onimq iwosan sq pe “o ni iba nla” – Matiu 8:14 ti o si wa ni ori akete aisan.

Arun iba a maa fi oju awqn eniyan gbolv ninu irora nla ti awqn ti o ba wa lori akete aisan yii ko ni ri ara, qrv ati ojulumq lati tqju rv ni iru akoko ti a n sq yii.

Bi wqn ze sq qrq iya yii fun Jesu ni O pa ohun gbogbo ti, O si lq si vgbv ibusun rv, eyi ti ki i zvlv nigba naa, ki vnikan tq vni ti o wa lori akete aisan lq. Matiu 8:15 tilv sq fun wa pe Jesu tun fi qwq le e lapa pvlu. Eyi jv ami ifv fun iya ti awqn tirv paapaa ko le sunmq. Bi Jesu ze fi qwq aanu ati ifv le lara ni o mq iru vni ti Jesu jv pe dajudaju Qlqrun ifv ni eleyii. Itan yii ko tan si bi iya-iyawo Peteru ze dide ti o n tvsiwaju lvnu izv iranzv rv. Ju izv iwosan iyanu yii ni ete pataki ti Jesu fi ze izv iyanu yi ni lati pe wa si izv isin Rv. Obinrin ti o wa ninu irora lori akete aisan ni bi izvju meloo svyin ni o ti dide ti o si n ba izv iranzv rv lq nipasv qrq ti Olugbala ti sq si aye rv. Iyanu nla ni eyi.

Obinrin yii le pinnu lati sun si ori ibusun fun igba div ti ko si vniti yoo binu si eyi, zugbqn lati fi vmi imoore rv han. Ohun ti Jesu ze fun-un o dide lqgan ni kiakia o si n tan ninu izv iranzv rv.

Page 8: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

A ka ninu Timoti keji 1:9a pe “Vni ti o gba wa la, ti o si fi ipe mimq pe wa, ki i ze ize gvgv bi izv wa, zugbqn gvgv bi ipinnu ati oore-qfv tirv,”

Qlqrun ti pe wa lati wa gbe igbe aye mimq eyi ti o tv siwaju di isin mimq. V jv ki a maa ranti pe kii ze tori izv isin wa ni a fi gba wa la zugbqn a gba wa la ki a le ze izv isin. Ipo isin wa ni Ijqba Qlqrun ni o le zq itumq at ete aye wa. A n sin Qlqrun ninu ayq ati imoore Rv lori ohun gbogbo ti o ti ze fun wa, oun ni o ni aye wa. Nigba ti a ba fi isin wa han si vlomiran ni yoo da bi vni pe si Qlqrun ni. Jesu wipe “Lootq ni mo wi fun yin, niwqn bi vyin ti ze fun qkan ninu awqn arakunrin mi wqnyi ti o kere julq vyin ti ze e fun mi” (Matiu 25:40). A pe wa lati sin Jesu nipasv isin wa si awqn eniyan. Izv isin wa si Qlqrun ni yoo jv ki a tan niwqn igba ti Jesu wipe “Vyin ni imqlv aye ilu ti a kq si ori oke kole fi ara sin. Bakan naa ni a ko le tan atupa ki a gbe si abv osunwqn bikoze sori qpa fitila, ki awqn ti n wqle ba le maa ri imqlv. Bakan naa jv ki imqlv rv tan ki wqn o le ri izv rere rv ki wqn o le yin Baba rv ti n bv lqrun logo.” (Matiu 5:14-16). A gbqdq dide lati tan fun Qlqrun. A n ze eyi ki a le sin Jesu lati sin awqn vlomiran. Vnikan wipe “Vni ti igbe aye rv ko fi isin han ko le sin lati wa laaye.” V jv ki A Dide ki A Tan…ati fun isin.

Raquel Contreras.

Page 9: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

AWQN IJVRII SI AGBARA QLQRUN Vni Qwq Ilie Coada

Vni Qwq Ilie Coada jv oniwaasu ijq Onitvbqmi ni Moldova. O fara rv jin pvlu awqn dukia rv lati dabobo awqn qdqbinrin ki wqn ma ba maa fi wqn zowo, ki wqn maa ba lo wqn ni ilokulo. O pese ilegbe fun awqn qdqbinrin wqnyi paapaa awqn qmq orukan, pe ki wqn maa gbe ibv ki wqn si ma a tvsiwaju lvnu vkq wqn, pvlu ibugbe ti awqn qdqbinrin ti wqn n lq si ile iwe ni igboro yoo maa de si lopin qsv tabi ni asiko ti wqn ba wa ninu isinmi qlqjq gbqqrq yoo ma de si. Coada gbe gbqngan kalv fun idanilvkq ki iye awqn qdqbinrin ti wqn yoo maa fori lugbadi ilokulo awqn qmqbinrin le dinku. Awqn qmqbinrin ti o si n kq lvkq le vvdvgbvta eniyan ni iye. O tun fun awqn qdqmqbinrin yii ni lanfaani vkq qfv ni ile iwe vkqsv qwq tabi ile iwe fasiti. Coada mu idagbasoke ba okowo keekeeke to fi pese izv fun awqn qdqmqbinin ati awqn agba-obinrin ninu ile lati fi tqju ara wqn ati awqn qmq wqn. Coada tun darapq mq orizii ile izv iransv latari ati fvmi ara rv wewu, ki awqn olowo ilo qmq nilokulo ma ze ri aaye lati lq maa ko awqn qmq nile awqn qmq orukan. Oun lo fi eto ki wqn ma ze maa lo awqn qdqmqbinrin ni ilokulo mq lelv pvlu bi o ze n ko awqn qmq orukan sqdq laibvru. O layq o si gbagbq pe “kosi ibvru ninu ifv” Lauran Bethell sq pe onwaasu Ilie jv apvvrv oniwaasu ijq onitvbqmi ti o n waasu qrq ti o si n fi ize kun-un pvlu irvlv laisi ariwo. O ti gba qpqlqpq qmq la kuro ni ipo vru ati ninu owo nabi (azvwo) ti o si jv awokqze fun Lauran ati awqn miiran. Oniwaasu Ilie ni o gba ami vyv fun a ja-jagbara fun Vtq qmq Eniyan ni qdun 2014.

Sela Koiya – PNG

Orilv Ede Paupa New Guinea ni agbegbe Mul Baiyer ni a bi Sela Koiya si ni idile Kristvni. O gba Jesu ni Oluwa ati Olugbala rv. O ze igbeyawo ni qdun 2003, nigba yii ni ile iwosan Tinsley Rural Baptist ze ayvwo izegun eebo fun-un ti wqn si ri pe o ni aisan eedi bi qkq rv ati awqn eniyan ze kq silv niyi. Arun yii ko ti wqpq nigba naa, bvvni oogun ko si fun iwosan aarun eedi. Ti o ba ti ni ikqlu yoo yara sare gba ile iwosan lq fun itqju. Arakunrin rv ati iyawo rv Susan Koiya ni o tvwq gbaa. Awqn agbajq eniyan kan ti wqn pe ara wqn ni qrv tootq (True Friends) n pese fun aini rv ni ti ara ati ti vmi. Arabinrin yii tqrq idarijin vzv rv nigba ti arakunrin rv ati Susan sq qrq Qlqrun fun-un. O gbagbq ninu agbara qrq Qlqrun ti o le ze iwosan pipe fun-un ni abv itqju awqn idile ti o n tqju rv ti wqn si n gbadura kikan fun iwalaaye rv. Ni qdun 2004, Onizegun oyinbo kan wa si ile iwosan ti wqn ti ze ayvwo fun-un, o si gba ni imqran lati lq fun itqju ni Lae fun itqju ti o peye. Bayii ni o lq ti wqn si da a duro si ile iwosan fun ozu mvrin ti o gba itqju pipe nigba ti iru itqju bvv ko ti wa ni agbegbe wqn ti o si gba iwosan pipe. Ni qdun 2005 – 2007 Sela di ajiyinrere lori agbara Qlqrun ti o wo o san fun awqn obinrin miiran ti aisan eedi n ba a finra. Iyawo arabinrin rv Susan koiya jv ozizv ni vka ti o n ze itqju awqn ti o ba ni aisan eedi ni ile iwosan Baptist Union of Paupa New Guinea ki o to di pe Sela ni arun yii. Eyi ni o fun Susan ni igboya lati tqju Sela ati awqn obinrin meje miiran ti o gba vri Sela gbq. Susan a maa gba wqn niyanju pvlu adura ninu itara, ti qpq wqn si ti ipasv bvv gba Kristi. Ni 2008 ni

Page 10: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

vniti o n dari vka awqn ti o n gba iwosan lori arun eedi fun wqn ni orukq (True Friends) qrv tootq ti adari yii si n ze iranlqwq owo fun wqn lozoozu fun igbaye-gbadun. Pvlu izv iranze vri Sela, awqn obinrin yii ti di qgbqn. Zugbqn awqn mvwaa ni koi ti ni anfani owo iranlqwq. Igbaye-gbadun yii ti Sela si n gbadura fun wqn ki wqn o le duro ninu Kristi ni aiko ara wqn si wahala miiran. Sela tv siwaju ninu vri rv, ti o si n ran wqn lqwq, lara ati lvmii ti o si maa n dari wqn si awqn qrv tootq fun igba-nimqran lore koore. Sela naa ti n zizv ni vka itqju yii ti o si tun darapq pvlu awqn ti o n ze izv qna lati mu owo wqle. O n dupv lqwq Qlqrun fun ifv tootq ati aanu Rv ti o jv ki o zeeze fun un lati wa ni aaye. Ni aidi wahala si vnikvni lqrun nipasv vka ile izv itqju alaisan eedi. Ni akotan, o ni oun ti ri izv ti Qlqrun gbe le oun lqwq ti oun yoo fi gba ere ni qrun. O dupv lori ohun gbogbo ti o ti zvlv sii eyi ti o ze iranlqwq fun-un lqpqpqpq. Ogo ni fun Qlqrun.

Rose Jabani, Zambia

Alaga: Southern Africa Region

Vgbv Obinrin Onitvbqmi ni Africa ti ran mi lqwq gvgv bi vnikan, wqn ran orilv ede wa Zambia naa lqwq lati dagba ninu Kristi. Orilv ede Zambia jv ilu ti o wa ni aarin gbungbun ila oorun orilv ede Afrika, orile ede Congo ni o wa ni apa ariwa rv, Tanzania ni aarin meji ariwa-ila-oorun, Malawi ni ila oorun, Mozmbique, Zimbabwe, Botswana ati Namibia ni guusu ti Angola si wa ni iwq oorun. Vgbv Obinrin Onitvbqmi ni Africa ti mu alafia, ifv ati irvpq wq ilv Zambia nipasv akitiyan wqn lati mu ki vgbv yii wa ni ilv Zambia. Ni akoko ibvwo alaga vgbv yi si ilv Zambia wqn gba awa obinrin niyanju lati kq vkq igbalode lori awqn vrq igbalode. Bayii obinrin ile Zambia ti ni imq vkq vrq igbalode, ti wqn si ti n lq si ori vrq ayelujara lati sq ohun ti wqn nilo lati sq. Ni akoko abvwo yii kan naa, wqn tun ze itvnumq lori qjq Adura Obinrin Onivbqmi ni agbaye ati Africa nitori eyi awqn obinrin Zambia ti fi ara wqn jin fun adura ti ififunni wqn si ti ni apvvrv ti o jqju. Vka iroyin vgbv yii ni agbaye kojv ki eti awqn obinrin Zambia di si awqn iroyin ati eto ti o yv, eyi si mu ki a lepin awqn ohun ti a n gbe ze pvlu awqn obinrin yooku ni Africa. Vgbv Obinrin Onitvbqmi Lagbaye ran wa lqwq ni Zambia lati gbe awqn eto kalv fun irolagbara awqn obinrin eyi ti o si ti mu izv ati ozi kuro laarin obinrin titi o fi de igberiko. A ti ze agbekalv gbqngan kan fun vkqzv qwq awqn obinrin ati qdq. Vgbv yii kan naa ni wqn ro mi lagbara (Rose Jabani) lati jv adari rere ni agbegbe wa titi de gbogbo Gusu Afrika.

Arojinlv Lori Qjq Adura ati Qrv

Adura jv pataki ninu igbagbq wa, oun gan-an si ni o wa ni aaringbungbun vka vgbv obinrin. Adura ni okun ti o so wa pq ninu itan vkq vgbv obinrin, ajqzepq wa ninu ayvyv adura wa qlqdqqdun ti a mq si Qjq Adura Lagbaaye.

Page 11: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

Bawo ni o ze bvrv? Ni qdun 1948 lvyin ti ogun agbaye keji kazv nilv ni awqn Obinrin Onitvbqmi mqkandinlogun pade ni ilu London, ni ilv England ti wqn si ka adura Oluwa papq. Ni aarin qjq mvta wqn ti di Vgbv ti a mq si European Baptist Women’s Union. Ni qdun 1950 awqn obinrin lati orilv ede mvtala pade ni Baptist World Congress wqn si gbq nipa iriri awqn obinrin ti wqn ti di vgbv yii ninu adura agbapq ati ibukun ti o n tvle wqn. Bayii ni wqn fimq-zqkan pe ki qjq kan wa fun adura ni qjq vti akoko ninu ozu kejila (1st Friday of December) eyi ti o bvrv ni December 1,1950. Ipolongo qjq yii ko pq to bi o ze yv tori ko si aaye lati kede qjq yii. Zugbqn lvyin igba div o di mimq kaakiri fun awqn obinrin. Qpqlqpq obinrin ni o jv pe irinajo jinjin ni fun wqn, ti awqn miiran yoo rin qpqlqpq ibusq fun qjq div lati darapq mq eto yii. Ko si aaye lati jiroro pvlu awqn vlvgbv wqn. Sugbqn bayii vrq igbalode ati itakun alatagba ayelujara ti sq ohun gbogbo di vrq. Lati darapq mq qjq adura qjq kan yii ki a si tun ni ijiroro ati ifarakinra pvlu awqn vlvgbv wa ti o n darapq mq eto yi lagbaaye. Ohun pataki miiran ti qjq Adura yii ni ni anfani ti a ni lati ba Qlqrun zowo nipasv qrv ti a n mu wa. Ilaji qrv yii ni o n lq si apo vgbv ni Kqntinvnti (Continent) ti ilaji yooku si n lq si vka vgbv ni agbaye. O le ma ye yin pe qna kan zozo ti vka vgbv yii ti n ri owo lati ze ohunkohun niyi ati fun Kontinvnti pvlu. Kii ze awqn vka meji ti a sq yii nikan ni wqn n wulo fun zugbqn qrv yii naa ni a fi n ze awqn izv iranzv pataki. Qrv yin yii ni a n lo fun awqn orizi izv pataki meji. Awqn Kontinenti a maa yan izv pataki fun zize ni ilu orilv ede wqn bakan naa ni vka vgbv obinrin lagbaaye naa maa n ze izv akanze pataki. Boya v ro pe qrv yin ko jamq ohun kan. Qlqrun le sq ohun kekere di pupq. V ranti itan izuakara meji ati vja wvwv ninu Bibeli. Bawo ni o ze zeese pe o bq vgbvvgbvrun eniyan o si tun svku. Qrv ti qmqkunrin kekere yqnda fun Qlqrun lati inu qkan ifv ni yi ti o to ti o si tun zvku rvpvtv. Izv akanze ti vka vgbv obinrin yan ni qdun yii pvlu qrv qjq adura ni lati ze iranlqwq fun igbaye-gbadun ni Moldova, eto yii yoo ran awqn obinrin ti o ni arun eedi ni Paupa New Guinea lqwq ati irolagbara awqn adari ni Afrika fun imq ati vkq ti o ye kooro. Lara awqn akanzv izv ti a ti ze svyin ni ipese vkq fun awqn obinrin ati awqn qmqde, ipese ounjv lati bq awqn obinrin ati qmqde ti ebi n pa, ipese ilegbe fun awqn obinrin ati awqn qmqde ti awujq ko naani, kikq awqn adari paapaa julq awqn qdqmqbinrin. Ki awqn obinrin ni izv qwq bi agbv tabi azq riran. Ohun ti o jv afojusun eto pataki yii ni lati ba aini awqn obinrin pade ti yoo si jv ki awqn obinrin de ipo adari ninu igbaye-gbadun. Mo ti ni anfani lati ze abvwo si awqn izv akanze fun qjq Adura Lgbaaye pvlu awqn miiran ni awqn qdun div svyin. Ni Nigeria a ri izv qgbin ewebv ti awqn obinrin kq eyi ti o si n mu owo wqle fun wqn, bakan naa ni wqn si tun n jv nibv pvlu. Ni Chile, a ze abvwo si ile itqju awqn arugbo eyi ti awqn Vgbv Obinrin Onihinrere Ijq Onitvbqmi gbe kalv lati tqju awqn arugbo ti ko ni vbi ti o le tqju wqn. O jv ayq ti o kun qkan wa lati ri ifv ti awqn olutqju yii n fihan si awqn arugbo wqnyi. A ti lq si Thailand pvlu ni agq awqn alarinkiri boya nitori ogun tabi wahala kan ni ilu wqn nibi ti wqn gbe beere fun owo iranlqwq lati ra vrq iranzq (sewing machine) fun awqn obinrin ti wqn n kq ni izv azq riran ati izv qna ti wqn yoo le ta wqn lati wa ounjv fun idile wqn.

Page 12: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

Ara qtq ni awqn izv akanze wqnyii. Qrv rv ati eyi ti a gba kaakiri agbaye ni a fi n ze OHUN NLA WQNYI. Adura ni a fi n ze OHUN NLA. Bi a ze n ze ajqyq Qjq Adura Lagbaaye ni qdun yii (2015) v jv ki a maa ranti awqn obinrin lati ilv Europe ti wqn pade ni qpqlqpq qdun svyin ati iyatq ti ipade wqn ti mu wa. V jv ki a sun mq Qlqrun ki a si maa gbadura daadaa ki ififunni wa jv eyi ti o dara lati fifun Qlqrun. Dona Goover

Akqwe/Akapo (2010-2015) Vka Vgbv Obinrin Onitvbqmi Lagbaaye (BWA Women’s Department).

Awqn Vbv Adura fun Vkun Kqqkan Africa:

1. Gbadura pe ki Qlqrun ba wa pa arun Ebola run patapata ni Iwq Oorun Africa. 2. V gbadura fun awqn akvkqq gboye ni awqn Fasiti wa ti wqn ko tii risv. 3. Gbadura fun imuduro eto izvjqba ni awqn orilv ede wqnyi, Central Africa

Republic, Sudan, Mali, Eastern Domecratic Republic of Congo atiGuinea Bissau. 4. V gbadura fun gbogbo awqn to lugbadi ikq Boko Haram ni apa oke qya pvlu

awqn miiran ni iwq oorun orilv ede adulawq. 5. V gbadura fun ifarabalv yan ohun to dara julq nipa sisq owo na ati zize

aimojuto awqn alumqni wa daadaa laarin awqn olori wa ninu ijq Onitvbqmi ni Africa.

6. V gbadura fun awqn to lugbadi awqn aisan ti kii sqtvlv fun ni ki o to rapala wqle bi arun vjv riru, rqlapa rqlesv, atqgbv, jvjvrv, arun eedi (HIV/AIDS, ikq fee ati aisan iba.

Asia

1. Gbadura fun isqkan ati irvpq laarin awqn ijq Onitvbqmi Indonesia bi wqn ze n palvmq lati gbalejo ipade nla ni Asia Pacific ti yoo waye ni qdun 2017 ati ti awqn obinrin ijq Onitvbqmini qdun 2018.

2. Gbadura fun awqn anfaani lati jvrii, ki wqn si waasu fun awqn vniyan ni Pakistan.

3. V gbadura fun awqn ijq to wa ni Hong Kong pe ki wqn le fi igboya kede alaafia ti Kristi mu wa bi o ti wu ki isvlv oselu ri.

4. V gbadura fun jijv olotitq nipa wiwaasu Kristi fun gbogbo eniyan, lati ori awqn qdq ni Sri Lanka pvlu awqn obinrin wqn.

5. V gbadura fun awqn Kristivni Japan pe ki wqn le lo qgbqn lati fisq Jesu di mimq si awqn eniyan orilv ede wqn, bi wqn ze n waasu ni akoko inira.

6. V yin Oluwa fun awqn ijq tuntun ti o n tvsiwaju pvlu ero lati fidi mulv ni awqn agbegbe ti awqn vya Haiyan Typhoon kqlu ni qdun 2013.

Caribbean

1. V gbadura fun awqn ozizv ti o ni oore qfv ifarajin lati ze izv nla fun Oluwa.

Page 13: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

2. Gbadura Vmi Mimq fun awqn eniyan to ti n sq ireti nu pe ki qwq qtun Qlqrun kaan wqn, ki O fun wqn lagbara lati le zizv ninu qgba ajara.

3. V gbadura fun itusilv awqn obinrin ti wqn ko jq bi vru nitori ati ma a ba wqn lopq lqna aitq.

4. Gbadura fun idahunsi atokewa lati dawq orisii arun duro ni Caribbean. 5. V gbadura fun awqn alaga ati awqn qmq Igbimq ati ni ibi gbogbo ki wqn ri ipo

wqn bi pe Qlqrun lope wqn. 6. V gbadura pe ki iwa vkq ile ma a gberu sii paapaa julq laarin awqn qdq, ki wqn

le fi ara wqn jin fun Oluwa patapata. Europe

1. V gbadura lodi si ogun ti ko ni itumq ati ija ki a le wa qna abayq si awqn izoro ozelu, qrq aje ati ti qlaju.

2. V gbadura fun awqn obinrin ni Europe pe ki Oluwa lo wqn bi ohun elo alaafia ni orilv ede, ninu idile ati ninu vbi wqn.

3. V gbadura fun awqn obinrin ati idile wqn paapaa awqn qdqmqkunrin ati qdqbinrin pe ki wqn o jv vni iyi vni vyv dipo ilepa awqn ohun asan aye yi.

4. Gbadura wipe ki awqn obinrin Europe ni iran lati wa qna ti o yv lati dojukq awqn ipenija awujq iwoyi, ati bi wqn ze le kq apejqpq awqn obinrin ninu ijq kqqkan lati ni ifarakinra pvlu Kristi.

5. V gbadura fun awqn obinrin to n gbe ni awqn orilv ede ti ko si alaafia, ti izv ko si, ti airina-airilo nba finra, ti ko si ireti qjq qla ti o dara fun awqn qmq wqn ati qdq gbogbo.

6. V gbadura fun awqn obinrin to n sin pe ki wqn duro laiyvsv, ki wqn si tun ni iriri ibukun Qlqrun ki ara wqn ba le tutu lati tvsiwaju ninu izv iranzv si awqn aladugbo wqn, pvlu awqn vgbqn wqn lqkunrin ati lobinrin.

Latin America

1. Gbadura fun awqn adari gbogbo awqn obinrin lapapq pe ki Qlqrun ran wqn lqwq lati ze awqn akanze izv ti yoo ru qkan awqn obinrin igberiko soke.

2. Gbadura fun isqdqtun vkq ihinrere fun awqn qdq, ki qpqlqpq wqn le ko ipa ti o yv ni awqn ijq gbogbo ni Latin America.

3. V gbadura fun bi wqn ti n fqwqsowqpq pvlu awqn eto ajihinrere UBLA ti vkun Latin America.

4. V gbadura fun ipalvmq ati ipade Kqnfrvnsi apapq awqn adari vkun kqqkan ti yoo waye laarin qjq kinni si qjq kvrin ozu kvsan–an qdun 2016 (September 1-4, 2016).

5. V gbadura fun awqn obinrin ijq Onitvbqmi bi wqn ti n zizv orilv ede wqn lati mu ki ozi, aimqkq-mqqka ati vbi kasv nilv ki wqn o si le ba aini awqn eniyan ti wqn n dari lvmi pade.

6. Vgbv UFBAL n fi qpv fun Qlqrun tori o pe qgqta qdun ninu izv isin, wqn n gbadura lati ma ze rvwvsi ninu izv isin wqn nipasv Vgbv Obinrin Onitvbqmi.

North America

1. V gbadura wi pe ki awqn obinrin North America maze gbagbe lati maa gbadura daadaa, fun awqn ti o n fi oju winna izoro nitori Orukq Jesu.

Page 14: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

2. V gbadura pe ki awqn obinrin ijq Onitvbqmi ati awqn ijq gbogbo le fi ifv Jesu han si awqn eniyan to sa asala fun vmi wqn ti wqn wa n farapamq si North America lqdqqdun.

3. Gbadura fun North America pe ki wqn le jv iriju to dara nipa awqn alumqni ti Qlqrun fun wqn ki wqn le lo fun awqn ti wqn ze alaini.

4. V gbadura fun awqn qmq Vgbv Obinrin to n dinku ni iye pe ki wqn wa oju Oluwa fun idari isqdqtun.

5. Gbadura fun awqn qdqlangba ati awqn qdq to ti n goke agba pe ki wqn ni-in lqkan lati tvsiwaju ki wqn maa dagba ninu Kristi ni aika ijvgabale to wa lawujq wqn si.

6. V gbadura fun ifvsvmulv awqn ohun vmi laarin awqn obinrin ijq onitvbqmi ni North America pe ki wqn maa tvsiwaju lati maa sapa wqn lati fi itara wqn ninu Oluwa han ninu qrq ati ize wqn.

South West Pacific

1. V gbadura fun awqn obinrin ijq Onitvbqmi ni Australia pe ki wqn tvju mq Oluwa ki isqji svlv ni ilv wqn.

2. V gbadura fun awqn obinrin ijq Onitvbqmi ni Papua New Guinea pe ki wqn le wa ni isqkan bi isv ihinrere naa ti n gbooro si ni awqn ileto ati awqn orilv ede.

3. V gbadura fun awqn obinrinm ijq Onitvbqmi ti Fijian ti wqn n gbe ni awqn igberiko to jinna pe ki Qlqrun mu qkan wqn le lati tvsiwaju lati maa sa ere ije naa laika idvyvsi wqn si.

4. V gbadura fun awqn obinrin to wa ni West Papua bi wqn ze n ni iriri igbesi aye tuntun ninu Kristi laarin awqn awujq musulumi.

5. V gbadura fun awqn obinrin ijq Onitvbqmi to wa ni New Zealand pe ki Qlqrun ru awqn qdqbinrin wqn soke fun idari ati isv iransv.

6. V jqwq gbadura fun ikq awqn adari BWUSWP bi wqn ze n zawari awqn obinrin ni gbogbo vkun naa ti wqn si n ze iranlqwq ati adura fun awqn obinrin ni gbogbo South West Pacific.

Awqn Vbv Adura Lapapq

1. V gbadura fun alaga Vgbv Obinrin tuntun BWAWD ti a yan ni qdun 2015 ninu ipade awqn oludari awqn obinrin ijq Onitvbqmi.

2. V gbadura fun akqwe/akapo tuntun fun BWAWD ti a yan ninu ipade awqn oludari awqn obinrin ijq Onitvbqmi.

3. V gbadura fun Patsy Davis, oludari agba fun BWAWD. 4. V gbadura fun awqn igbakeji awqn alaga wqnyi:

Africa: Joina Dhlula

Asia: Precy T. Caronongan

Caribbean: Yvonne Pitter

Europe: Aniko Ujvari

Latin America: Sarade Barrios

Page 15: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

North America: Moreen Sharp

South West Pacific: Sue Peters

5. V gbadura fun T.J. Wheeler, Igbakeji Oludari agba fun BWAWD.

Awqn Adari Isqkan Ijq Onitvbqmi Lagbaaye

1. V gbadura fun John Upton, Alaga BWA tuntun 2. V gbadura fun Neville Callam, Akowe Aba fun BWA.

Page 16: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

Awqn Akanze Izv Pataki: Qdun 2015

Orukq Akanze Izv: Bethania Foundation Alakoso: Ilie Coada Ipo: Oluzq Agutan ati Oludasilv Orilv ede: Moldova Apejuwe Akanze Izv: Akanze izv yii yoo wa jakejado Republic of Moldova- Awqn qna lati dena fifi eniyan zowo, lati daabo bo idile, qmqde, qmq orukan ile vkq jvle-o-sinmi ati awqn arugbo pvlu. Orukq Izv Pataki: Qrv tootq (True Friends) Alakoso: Susan Koiya Ipo: Adari Qrv Tootq Orilv ede: Paupa New Guinea (PNG) Apejuwe Izv Pataki: Eto yii wa fun kikq awqn obinrin ti o ni aarun eedi ati ikq fee lati mq ounjv ti o dara fun vni ti o ba ni aisan wqnyi, qna ti vmi ati ti ara fun igbe aye alafia. Wqn yoo tun kq awqn obinrin ni izv qwq. Awqn qgbqn (30) ni o wa nibv bayii nigba ti mvwaa ti yvra nitori qda owo. Orukq Izv Pataki: Baptist Women’s Union of Africa (BWUA) Leadersip Training Alakoso: Joina Dhlula Ipo: Alaga Vgbv Obinrin Africa Vkun: Africa Apejuwe Izv Pataki: Lati kq awqn adari ni qna ti vgbv tuntun miiran fi le bvrv ati qna lati ro awqn obinrin lagbara ti izv ati ozi yoo si kazv nilv de igberiko. Ti wqn yoo si le ze izv adari wqn deede. Orukq Izv Pataki: Continental Union Special Project Fund. Alakoso: BWA Women’s Department Executive Board. Apejuwe Izv: Owq ti a ba ri kojq yii ni a o fi ze iranlqwq fun izv pataki ni vkun kqqkan.

Page 17: DIDE, TAN IMQLV NIGBA TI A BA DIDE SOKE OUN YOO ... DOP - Yoruba.pdfItvsiwaju wa bi o tilv jv pe ko jafafa to nipa eto vkq agba fun awqn obinrin ati qkunrin kaakiri aye ni o n fi anfani

V fi Qrv ti v ba Gba Ranzv si awqn Vkun (Continent) ti O Ba Yv. North American

Baptist Women’s Union

BWA Women’s Department

ATTN NABWU

405; N. Washington St.

Falls Church, VA 22046

The checks need to be made

out to NABWU

Note: Canadians can give through

their member body. Please see

www.nabwu.org for the address.

Asian Baptist Women’s u Union Account Name:

CECILLIA MELANE

PALANDENG

US$ Savings Accout Number:

026221-142-6.

Name of Bank: Bank Central Asia.

Bank Address: BCA Cabang

Manado

JL. Sam Ratulangi Kav 17-19.

Manado 95000, Sulawesi Utara

Indonessia.

Swift Code: CENAIDJA

Caribbean Baptist Women’s

Union

Mrs. Marjorie Fletcher

Treasurer, CBWU

Duncans P>O>

Trelawny, Jamaica

European Baptist Women’s

Union

Mrs. Marjorie Fletcher

Treasurer, CBWU

Duncan P.O.

Trelawny, Jamaica

European Baptist Women’s

Union

Account Number: 272728

Bank Name: Spar-und Kreditbank

Evangelisch-Freikirchlicher

Gemeinden eG

BIC: GENODE51BH2

Postgach 1262

61282 Bad Homburg

Tel: 06172/980606-0

Baptist Women’s Union of Africa

Name of Bank

First Bank Corporation (FBC)

Account Number: 1025150550117

Swift code: FBCPZHWA

Branch: Zvishavane

Branch code: 8508

98 Robert Mugabe Way

Zvishavane, Zimbabwe

Baptist Women’s Union of

Latin America

Email UFBAL Treasurer

Ofelia Rendon de Tapuy at

[email protected]

Or Sara de Barrios UFBAL

President at:

[email protected] for

information on how and where

to wire your offering.

Baptist Women’s Union of the

South WestPacific

For more information on how to

Send in your offering please

contact

BWUSWP Treasurer, Fran Benfell

at [email protected]

Or [email protected].

Donations can now be made online

At www.bwawd.org – click on the

donate tab and then the “e-giving”

button. Donations may be sent

from anywhere in the world using

a credit card. You save time and

money with no transfer or wire

fees. A receipt will be sent with

50% designated to the appropriate

Continental Union and 50% to the

BWA WD.

International Officers 2015-2020

President: Elected at the July 2015

Leadership Conference in South

Africa. Check the BWA Women’s

Department website for name and

picture: www.bwawd.org

Secretary/Treasurer. Elected at

the July 2015 Leadership

Conference in South Africa. Check

the BWA Women’s Department

website for name and picture:

www.bwawd.org

Executive Director: Patsy Davis

Email: [email protected]

Vice Presidents:

Africa: Joina Dhlula

Email: [email protected]

Asia: Precy T. Caronongan

Email:[email protected]

om

Caribbean: Yvnne Pitter

Email; [email protected]

Europe: Aniko Ujvari

Email: [email protected]

Latin America: Sara de Barrios

Email:

[email protected]

North America: Moreen Sharp

Email: [email protected]

South West Pacific: Sue Peters

Email: [email protected]

BWA Women’s Department

Executive Asistant:

T.J. Wheeler

Email: [email protected]