Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 -...

20
COERLL - Yorúbà Yémi CC – 2011 The University of Texas at Austin 281 Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE OBJECTIVES: In this chapter you will learn: - About the school system - How to tell your friend about your course schedule - How to describe your school’s facilities to your friend - About life on campus

Transcript of Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 -...

Page 1: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

COERLL - Yorúbà Yémi CC – 2011 The University of Texas at Austin 281

Chapter 12 - Orí Kejì lá | CAMPUS LIFE

OBJECTIVES:

In this chapter you will learn: - About the school system - How to tell your friend about your course schedule - How to describe your school’s facilities to your friend - About life on campus

Page 2: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 282 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Àwæn örö (Vocabulary)

Nouns áàtì/ænà arts

adájô judge

agbára strength

agbègbè area

àjànàkú / erin elephant

akêgbê÷ colleague

àkôdá first to establish

àkôsórí memory verse

alákòóso governing council

àõfààní opportunity

apá section/arm

àpônlé exaggeration

àyè opportunity

àyëwò experiment

BÍ-EÈ B.A.

BÍ-¿ËDÌ B. Ed.

BÍ-¿ËSÌ B.Sc.

dáná cook

èsì result(s)

ëkô course(s)

÷lòmíìn another person

ÊM-EÈ M.A.

ÊM-¿ËDÌ M. Ed.

ÊM-¿ËSÌ M. Sc.

÷njiníà engineer

ibùgbé residence

ibùjókòó office

ìdárayá entertainment

ìdánwò examination

ìgboyè the degree of

Ilé-ìkàwé library

imö-ëkô education (as a discipline)

Ìmö-ëræ engineering (as a discipline)

Page 3: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 283 CC – 2012 The University of Texas at Austin

irun hair

ì«êjú minute

ì«irò math

ì«òro challenges, problems

kàõtíìnì canteen/restaurant

kêmíkà chemical

kíkêköô the study of

kôkô first

láàbù laboratory

lítíré«ö literature

obìnrin female

odindin whole

ojoojúmô everyday

oko farm

olùkô teacher

òmìnira independence

æmæwé a person who holds a Ph.D

oníròyìn journalist

òtítô truth

ósítëlì hostel

ækùnrin male

ôölù hall

òpópónà street

ötun new

politêkíníìkì polytechnic

sáyêõsì science

simêsítà/sáà semester

títì street

wákàtí hour

Noun Phrases bôölù àf÷sëgbá soccer

bôölù àfæwôgbá handball

bôölù àjùsáwön basketball

òfin àti ìlànà ìtô sônà rules and regulations

ëka ëkô branches of study

Page 4: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 284 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Ëka à«à àti ijó Department of Culture and Dance

Ëka ëkôæ olùkôni Faculty of Education

Ëka ëkô i«ê-ænà Faculty of Arts

Ëka ëkô i«ê àgbë Faculty of Agriculture

ëkô èdèe Yorùbá ëkô onípò àkôkô

Yoruba language course first degree

÷nu-önà àbáwælé entrance

ìbàmú pëlú òfin ilé-ìwé in accordance with university rules

igba ènìyàn 200 people

ilé aláràbarà house with designs

Ilé-ëkôæ sêkôñdìrì àgbà Senior Secondary School (SSS)

Ilé-ëkôæ sêkôñdìrì kékeré Junior Secondary School (JSS)

ilé-ìfowópamôsí bank

ilé gogoro tall building/tower

Ilé-ëkô aláköôbërë primary/ elementary school

ilé- ëkôæ sêkôñdìrì secondary school (high school)

ìmö i«ê àgbë agricultural science/farming

i«ê-ænà aláràbarà artistic work

ìwádìí ìjìnlë research

kíláàsìi sáyêõsì lêkí«ô tiatà

science class lecture theater

odidi ædún mêfà a whole/ good six years

oyè ìmö ìjìnlë Ph.D

ægbà àwæn ÷ranko zoo

ægbàa yunifásítì/kámpôösì university campus/campus

Æba‘bìrin Èlísábêëtì Queen Elizabeth

æmæ ilé-ëkô yàrá ìgbëkô

student classroom

tiatà ìdánilêköô lecture theatre

Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë University of Agriculture

Yunifásítì ti t÷kinôlôjì/ ìmö-ëræ University of Technology

Verbs jærö to enjoy the benefits

pegedé to succeed

rántí to remember

retí to expect

Page 5: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Àwæn örö (Vocabulary)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 285 CC – 2012 The University of Texas at Austin

rojô/ wíjô to complain

rôjú to hang in there

tán to end

yàtö different

yìn to praise

Verb Phrases (dá)_sílë establish

dojú kæ to be faced with

fi örö jomi toro örö discuss/ deliberate

gba ìgbéga to be promoted

kò rærùn not easy

kú i«ê well done!

má «èyænu don’t worry/never mind

múra sí ëkô be more studious

ri dájú wipe ensure that

«e kí n ri ÷ show what you can do

wö ___ lôrùn to be overwhelmed

Adjectives gbámú«é very good/very nice láìpê very soon

ní gêlê as soon as

Adverb káàkiri all around/everywhere

Other Expressions já fáfá smart

tí ó tóbi that is big

tó mòye that are knowledgeable

tó ñ gbowó r÷p÷t÷ making big bucks

wò ó! hey, you see…!

Page 6: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 286 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 1 - Ëkô Kìíní:

I lé-Ìwé (School System)

Ní ilë÷ Yorùbá, àwæn æmæ máa ñ bërë sí læ sí ilé-ëkô láti bí ædún mêfà. Ilé-ëkô aláköôbërë ni àwæn òbí máa ñ kôkô fi æmææ wæn sí. Ní ilé-ëkô aláköôbërë, orí«irí«i ëkô ni àwæn olùkô máa ñ kô àwæn æmæ. Ëkô bí ëkô èdèe Yorùbá àti èdè Òyìnbó. Àkôsórí tún wà lára ëkö tí àwæn æmæ ilé-ëkô aláköôbërë máa ñ kæ. Àwæn àkôsórí yìí jê önà tí àwæn olùkô máa ñ gbà láti fi jê kí àwæn æmæ ilé-ìwé mæ önà tí ènìyàn máa ñ gbà láti rántí nõkan. Odindi ædún mêfà ni àwæn æmæ máa ñ lò ní ilé-ëkô aláköôbërë kí wôn tó læ sí ilé-ìwé mêfà.

Ní ilé-ëkôæ sêkôñdìrì, àwæn akêköô ní àyè láti mú kíláàsì tí wôn bá fê. Àwæn æmæ ilé-ëkô tí wôn fêràn ì«irò ló máa ñ læ kíláàsì sáyêñsì. Àwæn tí ó bá fêràn lítíré«ô ni wôn máa ñ læ sí áàtì. Orí«irí«i ìdánwò ni àwæn akêköô máa ñ «e láti gba ìgbéga láti kíláàsì kan sí ìkejì. Apá méjì ni ëkôæ sêkôñdìrì pínsí. Apá aláköôkô ni sêkôñdìrì kékeré, ti ÷lêëkejì ni sêkôñdìrì àgbà. Ædún mêta mêta ni akêköô ñ lò ní apá köökan. Apá kejì jê ti àwæn àgbà. Lêyìn ödún mêfà ni ilé-ëkôæ sêkôñdìrì . Àwæn akêköô tí ó bá pegedé ni wôn ní àõfààní láti tësíwájú nínúu ëkôæ wæn.

Ilé-ëkô gíga ni ó tëlé ilé-ëkôæ sêkôñdìrì. Orí«irí«i ilé-ìwé gíga ni ó wà. Àwæn èyí tí ó wà fún àwæn tí ó kô nípà ìmö ëkô yàtö sí àwæn èyí tí ó wà nípa ì«ê æwô. Ilé-ëkô gíga kan tún wa tí wôn ñ pè ni ilé ëkôæ gbogbo-õ-«e tí a tún máa jê politêkíníìkì. Nínúu gbogbo ilé-ëkô gíga, ti yunifásítì ni ó ga jù. Àwæn tí ó bá fê di dókítà, àdajô, ömöwé àti bêë bêë læ ni ó máa ñ læ sí yunifásítì. Yunifásítì tún pín sí önà orí«irí«i. Yunifásítì tí ó wà fún ìmö i«ê àgbë ni wôn ñ pè ní Yunifásítì ti àgíríìkì. Èyí tí ó wà fún ìmö-ëræ ní wôn ñ pè ní Yunifásítì ti t÷kinôlôjì.

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

Answer the following questions in complete sentences.

1. Àti æmæ ædún mélòó ni àwæn æmæ ti máa ñ bërë ilé-ìwé lílæ ní ilë÷ Yorùbá? 2. Báwo ni àwæn olùkô ilé-ëkô aláköôbërë «e máa ñ ran àwæn akêköô lôwô láti le rántí

nõkan? 3. Ilé-ìwé wo ló tëlé ilé-ìwé aláköôbërë? 4. Irú kíláàsì wo ni àwæn akêköô tí wôn fêràn lítíré«ö máa ñ læ ni ilé-ëkôæ sêkôñdìrì? 5. Ilé-ëkô wo ni ó ga jùlæ nínú ètò ëkô ni ilë÷ Yorùbá?

Page 7: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 287 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 So àwæn örö tí ó bara mu ni öwô A àti öwô B papö. Match the words in column A with those in column B.

A B

onímö-ëræ memory verse

èdè math

àkôsórí arts

ì«irò language

áàtì engineer

ìdánwò experiment

adájô engineering

oníròyìn judge

ìmö-ëræ examination

àyëwò journalist

I«ê »í«e 3 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write the meanings of these words in Yorùbá.

1. àkôsórí 2. ilé-ëkô aláköôbërë 3. oníròyìn 4. ìmö-ëræ 5. àyè

Page 8: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô Kìíní (Lesson 1)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 288 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences.

1. Ní ilë÷ Yorùbá, àwæn æmæ máa ñ bërë sí læ sí ilé-ëkô láti bí ædún mélòó? a. méjì b. mêta c. márùn-ún d. mêrin

2. Ædún mélòó ni àwæn æmæ máa ñ lò ní ilé-ìwé aláköôbërë kí wôn tó læ sí ilé-ëkôæ sêkôñdìrì ?

a. márùn-ún b. mêfà c. mêrin d. méje

3. Orí«irí«i apá mélòó ni ilé-ëkôæ sêkôñdìrì pín sí? a. mêta b. mêrin c. méjì d. márùn-ún

4. Ilè-ëkô gíga tí ó ga jù ni? a. Politêkíníìkì b. Yunifásítì c. Ilé-ëkôæ sêkôñdìrì d. Ilé-ëkô gíga olùkôni

5. Àwæn tí ó bá fê di _____________ ni wôn máa ñ læ sí Yunifásítì. a. olùkô b. dókítà c. arán«æ d. aránbàtà

I«ê »í«e 5 Kí ni èròò r÷ nípa ëkô kíkô láàárín àwæn Yorùbá àti àwæn ará orílë-èdèè r÷?

Page 9: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 289 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 2 - Ëkô Kejì:

University Course Schedules

Ìsöröngbèsì (Dialogue) Tádé àti Bùsôlá ñ sörö nípa kíláàsì wæn ní Yunifásítì ti Texas ní Austin. Tádé ñ kêköô láti gba oyè nínú ìmö-ëræ. Bùsôlá ñ kô ëkô ìròyìn. Ó fê di oníròyìn tí ó bá parí ëkôæ rë. Ædún k÷taa Tádé àti Bùsôlá nìyí ní ilé-ëkô gíga. Wôn pàdé ni ìpàdé ÷gbê æmæ Áfíríkà (ASA – African Students Association). Àwæn méjéèjì fi örö jomitooro örö nípa ì«òro tí wôn ñ dojú kæ nínú ëkôæ wæn.

Bùsôlá: Tádé, õjê o mö pé kíláàsì márùnún ni mo ní ni simêsítà yìí?

Tádé: Háà! Hun ùn. Tìr÷ mà dára à. Kíláàsì márùnún ni èmi náà ni, pëlú láàbù. Mò ñ «e kákúlôösì, físíìsì, ëkô èdèe Yorùbá, kêmísírì àti sitatísííkì. I«ê náà wö mí lôrùn nítorí pe ojoojúmô ni mo máa ñ læ sí láàbù. Mo ñ «e àyëwò kan lôwô nísinsìnyí fún ìdánwò. N kò sì mæ bí mo ti máa rí kêmíkà tí màá lò pëlú àyëwò náà láti fi rí èsì tí mò ñ retí nínú àyëwò náà.

Bùsôlá: Háà! Mo yìn ê o. I«ê ñlá ni ò ñ «e. Èmi kò ní láàbù, bêë ni n kò sì ní i«ê ojoojúmô. Nítorí náà kò y÷ kí n máa rojô. Kú isê o, Tádé.

Tádé: O o, O «é o. Wò ó, ní«e ni mo ñ retí kí simêsítà yìí tán o jàre.

Bùsôlá: Má «è ìyænu Tádé, gbogbo rë ti ñ tán læ. Láìpê ìwæ náà yóò di ÷njíníà tó

Page 10: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 290 CC – 2012 The University of Texas at Austin

mòye, tó ñ gbówó r÷p÷t÷.

Tádé: Lóòótô ni o sæ Bùsôlá, «ùgbôn kíkêköô gboyè ÷njíníà kò rærùn rárá.

Bùsôlá: Tádé, má sæ bêë mô. Kò sí ëkô ìwé kankan tí ó rærùn rárá. »ùgbôn tí ènìyàn báá rôjú, ènìyàn á jæröæ rë.

Tádé: Otítô ni öröæ r÷ o, Bùsôlá. Mo ti gbô ohun tí o sæ. Màá rôjú.

Bùsôlá: Ó dára bêë. Jê kí n kô ÷ lórin tí bàbáa mi máa ñ kæ láti gbàwá níyànjú kí a ba à lè múra sí ëkôæ wa.

Bàtà r÷ á dún ko ko kà Bàtà r÷ á dún ko ko kà Bí o bá kàwé r÷, bàtà r÷ á dún ko ko kà Bùsôlá kàwé r÷, bàtà r÷ á dún ko ko kà Tádé kàwé r÷, bàtà r÷ á dún ko ko kà Bàtà r÷ á wô «÷r÷r÷ nílë o Bàtà r÷ á wô «÷r÷r÷ nílë o Bí o ò bá kàwé r÷ bàtà r÷ á wô «÷r÷r÷ nílë.

Tádé: Háà! Bùsôlá, O ti fún mi ní agbára ötun láti kàwé síi.

Bùsôlá: Ó dára o‚ alágbára ìwé.

I«ê »í«e 1 Sæ bêë ni tàbí bêë kô sí àwæn gbólóhùn wönyìí State whether the following sentences are true or false

BÊË NI BÊË KÔ

1. Tádé àti Bùsôlá ñ sörö nípa i«ê oko. ☐ ☐

2. Æmæ ÷gbê kan náà ni àwæn méjéèjì. ☐ ☐

3. Kíláàsìi Bùsôlá pö ju ti Tádé læ. ☐ ☐

4. Tádé ní i«ê÷ láàbù lójojúmô. ☐ ☐

5. Ëkô nípa ìmö-ëræ ni Tádé ñ kô. ☐ ☐

6. Bùsôlá ñ gba Tádé níyànjú pé kí ó má «àárë nípa i«ê÷ rë.

☐ ☐

7. Bùsôlá fê di oníròyìn. ☐ ☐

8. Láti kêköô gboyèe ÷njínìa rærùn púpö. ☐ ☐

9. Bùsôlá kæ orin fún Tádé láti mú u lôkàn le. ☐ ☐

10. Orin náà dára púpö. ☐ ☐

Page 11: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 291 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following sentences.

1. ________________ ni Tádé àti Bùsôlá? a. Ötá b. Æmæ ìyá c. Örê d. ¿bí

2. Bùsôlá fê di ______________ ní ëyìn öla? a. aláköwèé b. àgbë c. oníròyìn d. agb÷jôrò

3. ________________ ni Tádé nífëê láti dà? a. Oníròyìn b. Agb÷jôrò c. ¿njiníà d. Aláköwèé

4. Kíláàsì _______________ ni Bùsôlá ní ni simêsítà yìí? a. mêfà b. méjì c. mêrin d. márùn–ún

5. _______________ jê ökan lára i«ê tí Tádé ñ «e? a. Bàôlôjì b. Ëkô èdèe Yorùbá c. Kêmísírì d. Kákúlôösì

Page 12: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô Kejì (Lesson 2)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 292 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 »àlàyé orin yìí ní èdèe Yorùbá gêgê bí o «e rí i kà nínú àyækà òkè yìí. Explain this song in Yorùbá based on what you have read in the passage above.

Bàtà r÷ á dún ko ko kà Bàtà r÷ á dún ko ko kà Bí o bá kàwé r÷, bàtà r÷ á dún ko ko kà Bùsôlá kàwé r÷, bàtà r÷ á dún ko ko kà Tádé kàwé r÷, bàtà r÷ á dún ko ko kà Bàtà r÷ á wó «÷r÷r÷ nílë o Bàtà r÷ á wó «÷r÷r÷ nílë o Bí o ò bá kàwé r÷ bàtà r÷ á wô «÷r÷r÷ nílë.

I«ê »í«e 4 Sæ fún wa nípa ilé-ëkôö r÷ tàbí yunifásítìì r÷. Tell us about your school or your university.

I«ê »í«e 5 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Provide the meaning of the following words in Yorùbá.

1. oníròyìn 2. àyëwò 3. ìpàdé ÷gbê 4. jomitooro 5. gbà níyànjú

Page 13: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 293 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 3 - Ëkô K÷ta:

Facil i t ies

Yunifásítì t i Ìbàdàn

Orí«irí«i Yunifásítì ni ó wà ní orílë-èdè Nàìjíríà. Ökan pàtàkì ni Yunifásítì ti Ìbàdàn ní ìlú Ìbàdàn

ní ìpínlë Öyô. Òhun ni Yunifásítì àkôkô ní orílë-èdèe Nàìjíríà. Àwæn Òyìnbó aláwö funfun ni

wôn dá a sílë ní ædúnun 1948 bí ó tilë jê pé wôn yí orúkæ rë padà sí Yunifásítì ti Ìbàdàn lêyìn

ìgbà tí orílë-èdèe Nàìjíríà gba òmìnira ní ædúnun 1960.

Gbogbo önà ni ó wæ Yunifásítì ti Ìbàdàn. Bí ènìyàn bá ñ bö láti agbègbèe Sángo‚ ní gêlê tí

ènìyàn bá ti dé iwájúu Yunifásítì yìí ni ènìyàn á ti rí ÷nu-önà àbáwælé sí ilé-ëkô gíga yìí pëlú

i«ê-ænà aláràbarà. Òpópónà méjì ni ènìyàn á rí ní kété tí ènìyàn bá ti wælé: ökan fún àwæn tí ó

Page 14: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 294 CC – 2012 The University of Texas at Austin

ñ læ sí inú ægbà ilé-ìwé yìí nígbá tí ìkejì dúró fún àwæn tí wôn bá ñ jade kúrò nínú ilé-ìwé yìí.

Ilé gogoro ní ibi tí aago ti ó ñ ka wákàtí àti ì«êjú ni ènìyàn á kôkô rí tí ènìyàn bá ti wæ inú ægbà

ilé-ìwé yìí tí ènìyàn bá rìn síwájú díë. Nínú ilé tí ó wà ní tòsí ilé gogoro yìí, tíí «e ibùjókòó àwæn

alákòóso ægbà ni gbogbo à«÷ àti òfin ti ñ wá. Orí«irí«i ëkô ni wôn ñ kô àwæn àkêköô ní

Yunifásítì ti Ìbàdàn. Nínúu wæn ni ëkô onípò àkôkô tí amö sí BÍ-EÈ‚ BÍ-¿ËDÌ‚ BÍ-¿ËSIÌ àti àwæn

onípele ñlá tí ñ jê ÊM-EÈ‚ ÊM-¿ËDÌ‚ ÊM-¿ËSÌ, títí dé àwæn oyè imö ìjìnlë tí wôn ñ pè ní Ph.D.

Orí«irí«i ëka ëkô ni ó wà nínú ægbàa Yunifásítì ti Ìbàdàn. Láraa wæn ni a ti rí ëka ëkô olùkôni‚

ëka ëkô i«ê àgbë‚ ëka ëkô i«ê ænà àti bêë bêë læ. Nínú ægbàa Yunifásítì ti Ìbàdàn‚ orí«irí«I

ibùgbé tí a mô sí ôölù ni ó wà fún àwæn akêköô láti gbé. Àti ækùnrin àti obìnrin ni wôn ní

àõfààní láti gbé inú ôölù wönyí. Öölù Æbabìnrin Èlísábêëtì àti Ídíá ni ti àwæn obìnrin‚ Nnamdi

Azikiwe, Kùtì, Mellanby àti àwæn yòókù ni ti àwæn ækùnrin nígbá tí Tafawa Balewa jê ökan lára

ti àwæn akêköô onípele tó gajù.

»é àwæn àgbà bö wôn ní b’ômæ bá «e i«ê déédé‚ ó y÷ kí ó ní àsìkò àti «eré. Èyí túmö sí pé

lêyìn i«ê òòjô‚ àsìkò y÷ kó wà fún ìdárayá. Pápá ì«eré wà nínú ægbà Yunifásítì ti Ìbàdàn fún

bôölù àf÷sëgbá‚ bôölù àfæwægbá àti bôölù àjùsáwön. Bêë náà ni ægbà àwæn ÷ranko níbi tí a ti

lè rí ejò‚ kìnìún‚ öbæ‚ ìjàpá‚ ÷y÷ lórí«irí«i àti bêë bêë læ wà nínúu ægbà Yunifásítì ti Ìbàdàn. Ægbà

ilé-ìwée Yunifásítì ti Ìbàdàn tóbi ká má parô. Èyí ló jê kí n gbà pé àkôdá gan-an ni ní tòótô.

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

Answer the following questions in complete sentences.

1. Àwæn wo ni wôn dá Yunifásítì ti Ìbàdàn sílë? 2. Nígbà wo ni wôn dá Yunifásítì ti Ìbàdàn sílë? 3. Ní ilù wo àti ìpínlë wo ni Yunifásítì ti Ìbàdàn wà? 4. Kí ni orúkæ òpópónà tí a lè gbá wæ inú ægbà Yunifásítì ti Ìbàdàn? 5. Níbo ni à«÷ àti òfin ilé-ìwé yìí ti ñ wá?

Page 15: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 295 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 2 Parí àwæn gbólóhùn wönyí.

Complete the following sentences.

1. Orúkæ ôölù mélóò ni a dá nínúu àyækà òkè yìí? a. méjì b. mêfà c. mêrin d. mêtàlá

2. ____________ kò sí nínú àwæn öôlù tí a le rí nínú ægbàa Yunifásítì ti Ìbàdàn? a. Ôölù Æbabìnrin Èlísábêëtì b. Ôölùu Nnamdi Azikiwe c. Ôölùu Môremí

3. Ëka ëkô mélóò ni a dárúkæ lára àwæn ëka ëkô tí ó wà nínú ægbàa Yunifásítì ti Ìbàdàn? a. mêta b. méjì c. mêrin d. n kò mö

4. ________________ ni wôn yí orúkæ Yunifásítì ti Ìbàdàn padà? a. Ní ædúnun 1960 b. Ní ædúnun 1948 c. Kí ó tó dí 1960 d. Lêyìn ædúnun 1960

5. Òpópónà mélóò ni ó wæ inú ægbàa Yunifásítì ti Ìbàdàn? a. mêta b. méjì c. mêrin d. mêtàlá

Page 16: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 296 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Örö àdásæ (Monologue) Túndé ñ sörö nípa i lé gogoro ni i lé-ìwée rë (Túndé is talking about the tal lest building at his school.)

Öpölæpö ilé-ìwé ló wà ní tòótö‚ àmæ ti ilé-ìwée mi yàtö gan-an ni. Ilé-ìwée mi yàtö sí àwæn ilé-ìwé yòókù. Örö mi yìí kæjá àpônlé‚ bêë kì í «e àpônlu. Àwæn Yorùbá ní bí a kò bá dé oko baba ÷lomíràn wò‚ a kò lè mæ èyí tí ó tóbi jù nínú oko baba ÷ni àti baba ÷lomíràn. Èmi ti dé ilé-ìwé mìíràn‚ mo sì ti rí i dájú pé àjànàkú kæjá mo ri nõkan fìrí. Mo ti rí erin‚ mo sì mö pé erin ni. »é ti àwæn olùkô tí wôn gbámú«é ni kí n sæ ni tàbí ti àwæn ilé aláràbarà tí wôn wà ni kí n wí? Ká mú t’ëgàn kúrò‚ ká tún fi t’ëgàn kun, ilé-ìwé ni ilé-ìwéè mi. Yunifásítì ti Texas ní Austin ni mò ñ sæ. Gbogbo önà ni o lè gbà wæ ilé-ìwé mi yìí. Tí o bá wá gba iwájú ilé-ìfowópamôsí wælé, kí o kàn gbé ojú wo öôkàn‚ wà á rí ilé gogoro. Gígaa rë fê ë lè kan ærun. Ilé yìí ni wôn ñ pè ní “UT Tower”. Ibë gan-an ni gbogbo ètò àti à«÷ ilé-ìwée mi ti ñ wá. Ènìyàn kò gbædö gbókè wòran rárá. Tí o bá gbìyànjú dé iwájú ilé yìí tàbí tí o ní àõfààní láti wæ inúu rë‚ wà á kí ajé kú ìkàlê. Ilé-ìwéè mi dára t’ëgan lókù. Ìwæ gbìyànjú kí o wá‚ ìròyìn kò tó àfojúbà.

Page 17: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷ta (Lesson 3)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 297 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 3 Sæ bêë ni tàbí bêë kô fún àwæn gbólóhùn wönyìí State whether the following sentences are true or false

BÊË NI BÊË KÔ

1. Æmæ ilé-ìwée Yunifásítì ti Texas ní Austin ni Túndé. ☐ ☐

2. Önà kan ló wæ ilé-ìwée Túndé. ☐ ☐

3. Oko bàbáa Túndé ni Túndé ñ «àlàyé. ☐ ☐

4. Texas ni ilé-ìwée Túndé wà. ☐ ☐

5. Àwæn olùkæ ilé-ìwée Túndé kò mæ nõkan kan. ☐ ☐

I«ê »í«e 4 Kæ ìtumö àwæn örö wönyí sílë ní èdèe Yorùbá. Write the meaning of the following words in Yorùbá.

1. àpônlé 2. àpônlu 3. àjànàkú 4. gbámú«é 5. ilé aláràbarà 6. ëgàn 7. ilé-ìfowópamôsí 8. ilé gogoro 9. ìyànjú 10. àfojúbà

I«ê »í«e 5 Ó kàn ê‚ sæ nípa ilé-ìwé r÷ fún wa. Now it’s your turn, tell us about your school.

Page 18: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 298 CC – 2012 The University of Texas at Austin

Lesson 4 - Ëkô K÷rin:

Campus Life

Orí«irí«i Yunifásítì ni ó wà ni ílë÷ Yorùbá. Nínúu wæn ni Yunifásítì ìmö-ëræ, ìmö olùkôni, ìmö àgbë àti bêë bêë læ. Öjögbôn ni orúkö tí wôn ñ pe àwæn olùkô ilé-ëkô Yunifásítì. I«ê÷ wæn ni láti kô àwæn æmæ ilé-ëkô àti láti rí i dájú wí pé wôn «e i«ê÷ wön ní ìbámú pëlú òfin ilé-ëkô. Yàrá ìgbëkô ñlá ni wôn ñ pè ní tiatà ìdánilêköô. Àwæn lêkísö tiatà tí ó tóbi lè gba igba ènìyàn. Gbogbo ÷ka-ëkô ni ó ní tíátà ìdánilêköôæ tirë. Àwæn yàrá ìkàwé kéékèèké tún wà káàkiri ægbà ilé-ëkô. Àwæn ëka ëkôæ sáyêõsì máa ñ ní yàrá ìmö ìwádìí ìjìnlë. Ëka à«à àti ìjó ni gböngán ìdárayá. Nínúu gböngán ìdárayá ni wôn ti máa ñ «e ìdánwò «e-é-kí-ñ-rí-÷. Àwôn æmæ ilé- ëkô ní àyè láti wo eré àti ijó nínúu gböngán ìdárayá. Ibùgbé àwæn æmæ ilé-ìwé ni wôn ñ pè ní ôölù. Ôölù tàbí ósítëlì àwæn ækùnrin yàtö sí ti àwæn obìnrin. Púpö nínúu àwæn ôölù yìí ni wôn dá sílë pëlú orúkæ àwæn ènìyàn pàtàkì ní àwùjæ. Ôölù púpö ni ó wà ní ilé-ëkôæ Yunifásítì ti Ìbàdàn. Díë nínúu àwæn ôölù yìí ni Ôölu Æbabìrin Èlísábêëtì, Kútì, Awólôwö, Mellanby àti bêë bêë læ. Àwæn olùdarí ôölù kì í jê kí ækùnrin wæ ôölù àwæn obìnrin láti àárö títí di agogo mêrin. Àwæn alámójútó ôölù ní láti rí i wí pé àyíká ôölù mô tónítóní. Àwæn ibùgbé aládàáni wà káàkiri agbègbè ibi tí Yunifásítì bá wà. Àwæn ti aládàáni máa ñ wôn ju tí ìjæba læ. Àwæn ènìyàn lè wæ ibùgbé ti aládàáni ní àsìkò tí ó bá wù wôn. A«æ orí«irí«i ni àwæn æmæ Yunifásítì máa ñ wö. Wôn lè wæ a«æ òyìnbó, wôn sí tún lè wæ ti ìbílë. Púpô nínú àwæn obìnrin ní ilé-ëkô gíga Yunifásitì ni wôn máa ñ wæ «òkòtò. Àwæn æmæ ilé-ëkö gíga kì í sáábà rayè dáná. Nítorí ìdí èyí ni púpö nínúu wæn «e máa ñ læ sí kàõtíìnì láti læ ra oúnj÷ j÷. Yàtö sí ëkô ìwé, orí«irí«i ëkô ni àwæn æmæ máa ñ kô ní ilé-ëkö gíga Yunifásítì. Ìdi nìyí tí ó fi jê pe æmæ ní láti já fáfá tí ó bá fê wæ yunifásítì. Bí bêë kô irú æmæ bêë yóò dojú kæ ì«òro láti ödö àwæn olùkô àti àwæn akêgbê÷ rë ní ilé-ëkô. Ilé-ìwé gíga ti Yunifásítì gbayì láàárín àwæn Yorùbá. Gbogbo àwæn òbí ní wôn sì máa ñ fê kí æmæ wæn læ sí ibë. Tí æmæ bá kàwé gboyè ni ilé-ëkô gíga, iyì àti oríire ñlá ni fún àwæn òbí. Nítorí náà ni àwæn Yorùbá «e máa ñ kærin pé:

Yunifásítì dára níbi táwæn öjögbôn wà Ìbë lômô mi yó læ Olúwa yó mú un débë o.

Page 19: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 299 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 1 Dáhùn àwæn ìbéèrè wönyí ní ëkúnrêrê.

Answer the following questions in complete sentences.

1. Orí«i Yunifásítì mélòó ni a dárúkæ nínú àyækà yìí? 2. Kí ni orúkæ tí wôn ñ pe àwæn olùkô ní Yunifásítì? 3. Dárúkæ àwæn ôölù tí o rí nínúu àyækà yìí. 4. Õjê o rò pé ààyè wà fún àwæn akêköô láti «e ohun tí ó bá wù wôn ní Yunifásítì? »e

àlàyé. 5. Kí ni àwæn àõfààní tí ó wà nínúu kí ènìyàn læ sí Yunifásítì?

I«ê »í«e 2 Sæ bêë ni tàbí bêë kô sí àwæn gbólóhùn wönyí. State whether the following sentences are true or false.

BÊË NI BÊË KÔ

1. Yunifásítì dára láti læ. ☐ ☐

2. O dára kí æmæ já fáfá kí ó tó bërë÷ Yunifásítì. ☐ ☐

3. Kò pæn dandan kí æmæ læ sí ilé-ëkô aláköôbërë kí ó tó læ sì Yunifásítì.

☐ ☐

4. I«ê àwæn Öjôgbôn ní Yunifásítì ni láti rí i pé akêköô gbáradì fún ìdánwò.

☐ ☐

5. Àwæn òbí kò fêran kí æmæ wôn læ sí Yunifásítì. ☐ ☐

I«ê »í«e 3 Ó kàn ê, sæ fún wa nípa yàrá tí ò ñ gbé. Now it’s your turn. Tell us about your room.

Page 20: Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFEcoerll.utexas.edu/yemi/pdfs/yy_ch12.pdf · Chapter 12 - Orí Kejìlá | CAMPUS LIFE ... Yunifásítì ti àgíríìkì/ ìmö i«ê àgbë

Orí Kejì lá (Chapter 12) Ëkô K÷rin (Lesson 4)

COERLL - Yorúbà Yémi Page 300 CC – 2012 The University of Texas at Austin

I«ê »í«e 4 Parí àwæn gbólóhùn wönyí. Complete the following questions.

Gêgê bí mo «e rí i kà nínú àyækà òkè yìí ____________ jê ibi tí àwæn akêköô ti ñ kô ëkô.

____________ ni orúkæ ibi tí wôn ñ gbe. Àwæn akêköô máa ñ læ j÷un ní ____________tí ebi

bá ñ pa wôn. Orí«i a«æ ____________ ni wôn máa ñ wö. Àwæn obìnrin tilë máa ñ wæ

____________ nígbá mìíràn.

I«ê »í«e 5 »àlàyé orin yìí ní èdèe Yorùbá gêgê bí o «e rí i kà nínú àyækà òkè yìí. Explain this song in Yorùbá based on what you have read in the passage above.

Yunifásítì dára níbi táwæn öjögbôn wà Ìbë lômô mi yó læ Olúwa yó mú un débë o.